Bankulli – Ekorin Lyrics

Ekorin Lyrics By Bankulli

Ekorin kegbe orin iyin soke
So oba Oluwa mi
Koba mimo kogbawala
Ninu ijo mimo yi

Ekorin kegbe orin iyin soke
So oba Oluwa mi
Koba mimo kogbawala
Ninu ijo mimo yi

All – Ekorin kegbe orin iyin soke
So oba Oluwa mi
Koba mimo kogbawala
Ninu ijo mimo yi

Koba mimo kogba wa la
Ko fun wa la aranse
Kopa wa mo kuro ninu ese
Ko wa dariji wa

Ekorin kegbe orin iyin soke
So oba Oluwa mi
Koba mimo kogbawala
Ninu ijo mimo yi

Koba mimo kogba wa la
Ko fun wa la aranse
Kopa wa mo kuro ninu ese
Ko wa dariji wa

Koba mimo kogba wa la
Ko fun wa la aranse
Kopa wa mo kuro ninu ese
Ko wa dariji wa

Koba mimo kogba wa la
Ko fun wa la aranse
Kopa wa mo kuro ninu ese
Ko wa dariji wa

Koba mimo kogba wa la
Ko fun wa la aranse
Kopa wa mo kuro ninu ese
Ko wa dariji wa

READ ALSO:   Bankulli - Iye Lyrics