Burna Boy – Update Lyrics

Contentment Blog
Contentment Blog

Burna Boy Update Lyrics

Back to life, back to reality
Back to life, back to reality
Back to life, back to reality
Back to the here and now, oh-yeah

On a normal day, them no fit touch my energy (Kúrò n be)
Agba, ab’orí n ta yin? (L’Eko)
If I no get money na disability
Baba o, so forget mo ma ṣa e blocking

Má lọ sa o
Be’ri fun oga o
Agbabiaka o
Gbá update k’ole pa’wo
Won le, won o ba o
Take them do yanga o (Kúrò n be)
Malo wa o
Ọmọ ọba Jesu, ọkọ ashawo

Ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn
Ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn
Ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn
Ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn

Na my fruit of labor ni
Everyday, I dey spray money
To ba tele mi lo, my lady
You go see say, aye nbe l’ókè (L’Eko)
Mo kan gbé wan de be o (Okay now)
Fadila ke’tan, mo de fẹ fé e be yen o
Every woman give me special treatment
Wọn fi mi’le ni gba kan-kan-kan-kan-kan

Má lọ sa o
Be’ri fun oga o
Agbabiaka o
Gbá update k’ole pa’wo
Won le, won o ba o
Take them do yanga o (Nibo, nibo)
Malo wa o
Ọmọ ọba Jesu, ọkọ ashawo

Ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn
Ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn
(Agbabiaka, oh) Ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn (Mm)
Ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn-ahn

Back to life, back to reality
Back to life, back to reality
Back to life, back to reality
Back to the here and now, oh-yeah

Má lọ sa o
Be’ri fun oga o
Agbabiaka o (Ka o)
Gbá update k’ole pa’wo (Pa’wo)
Won le, won o ba o (Ba o)
Take them do yanga o (Kúrò n be)
Malo wa o
Ọmọ ọba Jesu, ọkọ ashawo (‘Shawo)